Table Of ContentIM¡L! TITUN
1
AKPA KINNI
Iwe kika fun awÛn agba kp£lu ilana ti £kÛ Bibeli.
Lati ¡wÛ: Dr. Kehinde O. Anifowoshe
Kp£lu OluranlÛwÛ re: Dr. Robert F. Rice
Atuny£wo yi wa lati ÛwÛ Pastor Ademola Abimbola
Bi a she n kÛ l£ta kekere:
a t o w i n
r e s u l j
k m f g b k p
Akiyesi Kpataki
Lati kÛni lÛna ti o k£s£ jari a gbÛdÛ t£le Ilana IkÛni. Ko
sheeshe lati kÛ eniyan ni £kÛ inu iwe yii daadaa lai j£ wi kpe
eniyan t£le awÛn igbes£ marun-un g£g£ bi a s£ tÛka r£ sinu Ilana
IkÛni. (4-15) ati ni oju iwe (20-21).
AwÛn iwe meji yii ImÛl£ Titun ati Ilana IkÛni ni a le ri ni ile
ish£:
!kÛ Agba, P. M. B. 5113, Ibadan, Nigeria
Ati
Heirs of God Christian Ministry, P.O. Box 6887,
Agodi, Ibadan.
Atuny£wo silebu fun akpa kinni:
Fun ak£kÛÛ lati tuny£wo (she atuny£wo) nigba gbogbo.
a à o i e u
ta tà to ti te tu
wa wà wo wi we wu
na nà no ni ne nu
ra rà ro ri re ru
sa sà so si se su
la là lo li le lu
ka kà ko ki ke ku
ma mà mo mi me mu
fa fà fo fi fe fu
gba gbà gbo gbi gbe gbu
kpa kpà kpo kpi kpe kpu
ba bà bo bi be bu
L!TA
aA bB dD eE £!
fF gG gbGb hH iI
jJ kK lL mM nN
oO Û¡ kpKp rR sS
shSh tT uU wW yY
ADURA OLUWA
Baba wa ti n b£ li Ûrun, ÛwÛ ni forukÛ r£. Ki ijÛba r£ de. If£ tir£
ni ki a she laye, bi wÛn ti n she lÛrun.
Fun wa lounj£ oojÛ wa lonii. Dari £sh£ wa ji wa, bi a ti n dari
ji awÛn to she wa.
Ma fa wa sinu idanwo, shugbÛn gba wa lÛwÛ bilisi: Nitori
ijÛba ni tir£, Agbara ni tir£, Ogo ni tir£ lailai. Amin.
AwÛn iwe meji yii ImÛl£ Titun ati Ilana IkÛni ni a le ri ni ile ish£:
Eko-Agba, P.M.B. 5113, Ibadan, Nigeria
Ati
Heirs of God Christian Ministry, P.O. Box 6887,
Agodi, Ibadan.
Literacy International
1800 S. Jackson Avenue
Tulsa, OK 74107, USA
([email protected])
ImÛ×l£Ø Titun
Akpa Kinni-in - !kÛ 1-30
Lati ÛwÛ:
Dr. Kehinde O. Anifowoshe
Kp£lu oluranlÛwÛ r£:Ø
Dr. Robert F. Rice
!ni ti o she atuny£wo yi ni:
Pastor Ademola F. Abimbola
AwÛn Ayàwòrán: B. Okosi & T. Yekeen
Ìfihàn l£ta titun nìwÛn yi:
1. a, o, t, w 11. -- 21. kp
2. i, Û 12. j, J, O, ¡ 22. --
3. n 13. £ 23. b, B, !
4. -- 14. k 24.
5. r 15. -- 25. sh
6. e 16. m 26. L£ta Nla
7. s 17. f 27.
8. u 18. gb 28. g
9. -- 19. -- 29. d
10. l 20. y 30.
Edition 2009: Copyright © 2009 Literacy International
All rights reserved.
Syllabaire diffusé par:
Alliance Bibllique du Bénin
03 B.P. 1101 Cotonou, Rép. du Bénin
Tél.: (+229)21380052
¡R¡ ISHAAJU (AK¡S¡)
Àgbàlagbà ti o ba mÛØwéékÛ ti o si mÛ×wéékà wulo ni ile
¡lÛrun.
Iru àgbàlagbà b££ yoo le mÛ itumÛ awÛn ofin oril£-ede r£,Ø
yoo si le kpa awÛn ofin oril£-ede r£ mÛ. Kp£lu agbara lati kàwé ati
afikun imÛ, o le ran oril£-ede ati awÛn ashaaju r£ lÛwÛ.
Àgbàlagbà ti o ba mÛØwéékà ni lati tun lagbara ninu igbagbÛ
nikpa kika ÛrÛ ¡lÛrun. O tun le j£ oluranlÛwÛ fun Oniwaasu r£ ati
awÛn Ûmo-ijÛ nigba ti o ba n ka ÛrÛ ¡lÛrun funrar£.
¡rÛ ¡lÛrun sÛ wi kpe “Nitori naa mo gba yin niyanju shaaju
ohun gbogbo, kpe ki a maa b£b£, ki a maa gbadura, ki a maa
sìkp£Ø, ati ki a maa dúkp£ × nitori gbogbo eniyan; fun awÛn Ûba, ati
gbogbo awÛn ti o wa ni ikpo giga; ki a le maa lo aye wa ni idak£j££
ati kp£lØ £ × ninu gbogbo iwa-bi-¡lÛrun ati ìwà àgbà”.
Gbogbo onigbagbÛ gbÛdÛ j£ £ni ti o maa n× ka Bibeli déédé.
! j£ ki a ran ara wa lÛwÛ lati le kàwé ati le kÛØwé. OnigbagbÛ ti o ba
mÛØÛ×kÛ-mÛØÛ×kà gbÛdÛ kÛ, o kere kpatakpata, £nikan ti ko le kàwé.
“Ki £ni ti o mÛw£ kÛ £lomiran” nikpa shishe b££ a o ran gbogbo
eniyan lÛwÛ lati mÛwØ £ × ka.
ImÛ×l£Ø Titun wa fun bi a she n kÛ onígbàgbÛ× bi o she le ka
Bibeli r£Ø. AwÛn iwe méjì tabi m£×ta wa ti akpakpÛ £kØ Û× wÛn j£ ÛgÛta
(72). OlukÛ ni lati t£le iwe Ìlana ÌkÛni ki o ba le ni oye awÛn £kÛ inu
iwe naa.
AwÛn l£×tà nla ni a fi shaaju ninu £kÛ k£rinlelogun (26). AwÛn
ÛØrÛØ inu Bibeli b£Ør£Ø kp£lu £ØkÛ× kejila, ti o fi orukÛ JESU han. !s£
Bibeli kan wa fun olukÛ lati ka l£hin £kÛ kÛÛkan.
NÛnba (iye), Ishiro, ati l£ta kikÛ ni a n kÛØ ninu awÛn £kÛ
k£talelÛgbÛn (33) ati £kÛ k£rinlelÛgbÛn (34). AwÛn £kÛ nikpa eto
ilera ati ish£ agb£ wa ni £kÛ karudinlogoji (35) titi de £kÛ
k£rindinlaadÛta (46). AwÛn itan lati inu Bibeli ti a ti ke kuru ni o wa
ninu awÛn £kÛ karundinlogoji (47) titi de £kÛ ÛgÛta (72).
2
KPATAKI:
Ki o to le kÛ eniyan ni àkÛ×yege, o ni lati t£lØ é iwe ètò Ìlana
ÌkÛni. Eniyan ti yoo kÛ awÛn £kÛ wÛnyi ko le she e lÛna £tÛ bi ko ba
farabal£ ka ati she “ohun ti olukÛ sÛ” ninu iwe Ìlana ÌkÛni.
OlùkÛ× naa ni lati kaa, o si ni lati gbáradì fun ati kÛni ni £kÛ, ki
o to maa kÛ awÛn ak£kÛÛ r£. Ki o kÛ eniyan g£g£ bi “Ìgbés£Ø
marun-un” ati awÛn ilana miran ti o wa ninu iwe Ìlana ÌkÛni.
ÀwÛn òfin fun ìkÛn× i ti o k£s× £járí:
1. SÛØrÛØ kp£Øl£×kp£Øl£.× Ni ÛØyàyà ki o si ni it£riba.
2. SÛrØ Û Ø niwÛnØ -tun-wÛnsi.
3. Ri i wi kpe o n gba awÛn ak£kÛÛ r£ níyànjú nigba gbogbo. Yin in
nigba gbogbo fun agbara r£. Ma she bínú nitori ashishe.
4. Ma she sÛ wi kpe “B££kÛ, o kuna. She o ò mÛ eyi ni?”
5. Ni ìr£lØ £Ø, fi Ûla fun ak£kÛÛ r£. Ka a kun £gb£ £ r£; ma she ro ara re
si Ûga.
6. Ma she fi awÛn ashishe awÛn ak£kÛÛ r£rin-in, ma si she gba ki
awÛn £lomiran fi wÛn r£rin-in.
7. F£ràn ak£kÛÛ r£ ki o si sÛ fun un wi kpe o le mÛwe kiakia.
RANTI:
Ko she e she lati kÛ eniyan ni £kÛ inu iwe yii daadaa lai j£ wi
kpe eniyan t£le awÛn “Igbes£ marun-un.” Ki o to le kÛ eniyan
daadaa, olukÛ gbÛdÛ kÛ awÛn “Igbes£ marun-un” fun kikÛ £kÛ. Wo
ètò Ìlana ÌkÛni kp£lu. AwÛn £kÛ inu iwe akÛkÛ ni a she kikÛni kp£lu
awÛn “Igbes£ marun-un” lai tÛ ilana miran.
Gbadura -- Shishe -- Waasu
3
ÌLANA FUN KIKO NI NI EKO
BI A SHE N K¡NI ATI BI A SHE N J!RI
A. BI A SHE N J!RI
I. Igbaradi lati j£ri
II. Ohun ti onigbagbÛ wi
B. BI A SHE N K¡NI
I. Mímúrasíl£
II. Igbaradi fun iwe-kika
III. Ohun ti olukÛ sÛ.
IV. Bi a she n× kÛ×ni ni iwe-kikÛ
V. Ish£-× ilé
VI. L£ta nla-nla
IKPARI
A. BI A SHE N J!RI
I. Igbaradi ati J£ri
Ohun ti o she kpataki nikpa ihinrere £kÛ agba ni lati kÛ ak£kÛ
r£ bi a ti nka bible ki a le ti ikpas£ r£ mu ij£ri ninu ijÛ gbooro sii.
OlukÛ gbÛdÛ mura sil£ fun anfaani ti o le ni lati j£ri ni akoko £kÛ
kÛÛkan.
Bi o she n ran ak£kÛ r£ lÛwÛ lati kawe, o le she awÛn nnkan
£mi. OlukÛ gbÛdÛ nif£ ak£kÛ. Bib£r£ ati kpikpari £kÛ kp£lu ÛrÛ
¡lÛrun ati adura le shil£kun ij£ri. OlukÛ ti o ba fi ara r£ jin yoo
kpal£mÛ fun £kÛ r£ gbogbo kp£lu adura ki o to b£r£ kp£lu ak£kÛ.
Ij£ri olukÛ l£yin £kÛ kÛÛkan she kpataki fun iru £kÛ b££. !s£
Bibeli wa ni oju iwe keji £kÛ kÛÛkan. OlukÛ le ka £s£ Bibeli fun
ak£kÛ l£yin £kÛ kÛÛkan tabi ki o ka £s£ Bibeli miran lati inu Ûkan
ninu awÛn ihinrere. B£r£ lati £kÛ kejila ni ibi ti o fi orukÛ Jesu han ati
ninu awÛn £kÛ ti o t£le ni a gbarale Bibeli, olukÛ gbÛdÛ shetan nigba
kugba lati gbe Jesu ga ki ak£kÛ lee ri ki o si gba A gbÛ. Jesu sÛ kpe
4
“Bi a ba gbemi soke (Lori igi agbelebu) emi yoo fa gbogbo eniyan
sÛdÛ emi tikalara mi”. KikÛni laisi ij£ri ko kun oju osunwÛn. Ij£ri
laisi ish£, ni ÛkpÛlÛkpÛ igba yoo kuna lati mu iyikpada Ûkan wa
SugbÛn adura, if£ si ish£ sishe ati ij£ri, awÛn m£t££ta yii yoo fun wa
ni àyè lati jèrè Ûkan ÛkpÛlÛkpÛ fun Kristi.
Lati ib£r£ £kÛ, ran ak£kÛ lÛwÛ lati wa ni ìd£rØ a ati ìrÛrØ ùn.
Nigba naa ni yoo farabal£ lati gbÛ ij£ri ti olukÛ yoo j£ l£yin £kÛ. Lati
fi ihinrere ni £kÛ han, awÛn ilana yii yoo wulo.
II. Ohun Ti OnigbagbÛ Wi
Bi o ba kÛni kp£lu adura ati if£ Kristi ak£kÛ yoo maa bi ara r£
ni ibeere yi lóókan aya r£: “Eeshe ti olukÛ mi fi dara bayi? Eeshe ti
o fi ni if£ si mi to yii?” OlukÛ yoo beere ibeere yi l£yin £kÛ akÛkÛ “N
j£ o mÛ idi ti awa onigbagbÛ n fi n kÛ eniyan bi a she kawe?” OlukÛ
sÛ kpe “A n se eyii nitori Jesu f£ ki a she b££. Jesu ni asiwaju wa
oninu-ire ti o kÛ gbe laye. O wo alaisan san, O bÛ awÛn ti ebi n× kpa,
o la oju afÛju ... shugbÛn ju gbogbo eyi lÛ, o f£ mi to b£ g££ ti o fi jiya
ti o si ku fun £sh£ mi ati tir£ kp£lu. Jesu ku g£g£ bi etutu ¡lÛrun fun
gbogbo eniyan. L£yin naa, ¡lÛrun ji Jesu dide kuro ninu oku, o si wa
kp£lu ¡lÛrun Baba loke Ûrun. O lee dari awÛn £s£ wa jin wa ki o si fi
alaafia Ûkan fun wa...... Mo f£ ki o mo-Ûn, ki o si mÛ bi aa ti ka itan
r£ ninu Bibeli. Jesu ni olugbala mi, o si lee j£ olugbala r£ kp£lu.”
Nikpa kikÛni kp£lu if£ wa aye lati kÛ× ak£kÛÛ nikpa Kristi. Jij£
Ûr£ si ak£kÛo r£, ki o ba lee fÛkan tan Û, yoo shi il£kun Ûr£ laarin
yin. O lee j£ Ûna si ij£wÛ Kristi kp£lu.
L£yin kikÛ £kÛ keji, kp£lu iyin ati iwuri, o she tan fun ij£ri
£l££keji. Bi ó ba léè ka dikpo ki o maa sÛÛ l£nu lasan, o sÛ bayii:
“Mo ti sÛ fun Û nikpa agbayanu if£ Jesu, £niti o ku fun wa ti o si wa
laaye nisisiyii fun wa. ! j£ ki n× ka itan iyanu kan fun yin lati inu
Bibeli. Bi oò ba lee kawe, afÛju ni Û. ShugbÛn bi o ba ti kpari £kÛ
yi, oó léè ka itan yi funra-r£. Itan yii ni itan Ûkunrin kan ti a bi ni
afÛju.” (Johanu 9:1-7, 35-41)
Ij£ri olukÛ l£yin £kÛ kÛÛkan ni o she kpataki julÛ ninu £kÛ kikÛ
fun ij£ri r£. OlukÛ léè ka £s£ Bibeli fun awÛn ak£kÛ l£yin £kÛ kÛÛkan.
5
O si lee ka ninu ihinrere miran tabi ibomiran ninu Bibeli. Dahun
awÛn ibeere iyanu ti awÛn ak£kÛ lee beere. Fetisil£ fun !mi MimÛ.
!niti o lee dari r£ lati sÛ ohun ti o y£ lati sÛ ohun ti o si lee ran Û lÛwÛ
lati maa sÛ ohun ti ko yee.
B. BI A SHE N K¡NI
I. Mímúrasíl£
Ki o to maa kÛ ak£kÛ r£, sÛ fun-un kpe iwÛ f£ ki oun naa kÛ
£nikan ni mi-mÛ-Ûn-kÛ ati mi-mÛ-Ûn-ka, l£yin igba ti ak£kÛ naa ba ti
mÛ iwe ka tan. G£g£ bi ak£kÛ r£ she ri iranlÛwÛ gba ni ÛØf£, b££ naa
ni oun naa se gbÛdÛ ni ayÛ lati ran £lomiran lÛwÛ lati lee kawe.
Bi a she n kÛ agbalagba yatÛ si bi a she n kÛ awÛn ÛmÛdé.
Agbalagba wa lati k£kÛ nitori kpe o ti Ûkan r£ wa ni. A ko fi agbara
mu-un. ¡kÉ pÛØlÛkpÛ agbalagba ni won ro wi kpe awÛn ko le mÛØwé, ti
wÛn si nberu wikpe awÛn yoo kuna. SugbÛn shaa, awÛn
agbalagba f£ lati tete kÛ ekÛ. Nitori naa, ak£kÛÛ agba yoo beere
lati £kÛ kinni-in. A ko f£ sh£ ak£kÛÛ wa. A f£ ki o tun kpada wa lati
wa maa kÛ £kÛ sii. Nitori naa, maa t£le awÛn ilana wÛnyi.
1. Maa sÛrÛ kp£l£ kp£l£. J£ Onít£ríba.
2. Maa fun ak£kÛÛ r£ ni igboya igba gbogbo. Ma she gbagbe lati
maa yin fun igbiyanju r£. Mashe j£ ki inu bi Û bi ak£kÛÛr£ ba
she àshìshé.
3. J£ onír£lØ £Ø, maa bÛØwÛØ fun ak£kÛ r£Ø. Mu ak£kÛÛ r£ g£g£ bi ara r£,
mashe shebi Ûga fun ak£kÛÛ r£.
4. Ma maa fi ak£kÛ r£ r£rin tabi ki o j£ ki £lomiran fi wÛn r£rin. Ma
she kan ak£kÛÛ r£ lojù, mà she faa s£yin.
5. F£ran awÛn ak£kÛÛ, ki o si maa fun won ni igboya kpe wÛn le
mÛ-Ûn kÛ, mÛ-Ûn ka. J£ ki £kÛ naa larinrin.
6. Ti o ko ba le kÛni, wa £lomiran lati ran Û lÛwÛ, tabi she eto lati
kÛ awÛn ak£kÛÛ ni igba miran.
6